Quran with Yoruba translation - Surah Adh-Dhariyat ayat 53 - الذَّاريَات - Page - Juz 27
﴿أَتَوَاصَوۡاْ بِهِۦۚ بَلۡ هُمۡ قَوۡمٞ طَاغُونَ ﴾
[الذَّاريَات: 53]
﴿أتواصوا به بل هم قوم طاغون﴾ [الذَّاريَات: 53]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ṣé wọn sọ àsọọ́lẹ̀ nípa rẹ̀ láààrin ara wọn ni? Rárá o! Ìjọ olùtayọ-ẹnu-àlà ni wọ́n ni |