Quran with Yoruba translation - Surah Adh-Dhariyat ayat 52 - الذَّاريَات - Page - Juz 27
﴿كَذَٰلِكَ مَآ أَتَى ٱلَّذِينَ مِن قَبۡلِهِم مِّن رَّسُولٍ إِلَّا قَالُواْ سَاحِرٌ أَوۡ مَجۡنُونٌ ﴾
[الذَّاريَات: 52]
﴿كذلك ما أتى الذين من قبلهم من رسول إلا قالوا ساحر أو﴾ [الذَّاريَات: 52]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Báyẹn ni (ọ̀rọ̀ ṣe rí)! Òjíṣẹ́ kan kò wá bá àwọn t’ó ṣíwájú wọn àfi kí wọ́n wí pé: "Òpìdán tàbí wèrè ni |