Quran with Yoruba translation - Surah AT-Tur ayat 18 - الطُّور - Page - Juz 27
﴿فَٰكِهِينَ بِمَآ ءَاتَىٰهُمۡ رَبُّهُمۡ وَوَقَىٰهُمۡ رَبُّهُمۡ عَذَابَ ٱلۡجَحِيمِ ﴾
[الطُّور: 18]
﴿فاكهين بما آتاهم ربهم ووقاهم ربهم عذاب الجحيم﴾ [الطُّور: 18]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Wọn yóò máa jẹ ìgbádùn pẹ̀lú ohun tí Olúwa wọn fún wọn. Àti pé (Allāhu) yóò ṣọ́ wọn nínú ìyà iná Jẹhīm |