Quran with Yoruba translation - Surah AT-Tur ayat 35 - الطُّور - Page - Juz 27
﴿أَمۡ خُلِقُواْ مِنۡ غَيۡرِ شَيۡءٍ أَمۡ هُمُ ٱلۡخَٰلِقُونَ ﴾
[الطُّور: 35]
﴿أم خلقوا من غير شيء أم هم الخالقون﴾ [الطُّور: 35]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Tàbí wọ́n ṣẹ̀dá wọn láì sí Aṣẹ̀dá? Tàbí àwọn ni wọ́n ṣẹ̀dá ara wọn ni |