Quran with Yoruba translation - Surah AT-Tur ayat 36 - الطُّور - Page - Juz 27
﴿أَمۡ خَلَقُواْ ٱلسَّمَٰوَٰتِ وَٱلۡأَرۡضَۚ بَل لَّا يُوقِنُونَ ﴾
[الطُّور: 36]
﴿أم خلقوا السموات والأرض بل لا يوقنون﴾ [الطُّور: 36]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Tàbí àwọn ni wọ́n ṣẹ̀dá àwọn sánmọ̀ àti ilẹ̀? Rárá o, wọn kò màmọ̀ dájú ni |