Quran with Yoruba translation - Surah AT-Tur ayat 37 - الطُّور - Page - Juz 27
﴿أَمۡ عِندَهُمۡ خَزَآئِنُ رَبِّكَ أَمۡ هُمُ ٱلۡمُصَۜيۡطِرُونَ ﴾ 
[الطُّور: 37]
﴿أم عندهم خزائن ربك أم هم المصيطرون﴾ [الطُّور: 37]
| Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Tàbí lọ́dọ̀ wọn ni àwọn àpótí ọrọ̀ Olúwa rẹ wà? Tàbí àwọn ni olùborí  |