Quran with Yoruba translation - Surah Al-Qamar ayat 6 - القَمَر - Page - Juz 27
﴿فَتَوَلَّ عَنۡهُمۡۘ يَوۡمَ يَدۡعُ ٱلدَّاعِ إِلَىٰ شَيۡءٖ نُّكُرٍ ﴾
[القَمَر: 6]
﴿فتول عنهم يوم يدع الداع إلى شيء نكر﴾ [القَمَر: 6]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ṣẹ́rí kúrò ní ọ̀dọ̀ wọn. Ní ọjọ́ tí olùpèpè yóò pèpè fún kiní kan tí ẹ̀mí kórira (ìyẹn, Àjíǹde) |