Quran with Yoruba translation - Surah Al-Waqi‘ah ayat 82 - الوَاقِعة - Page - Juz 27
﴿وَتَجۡعَلُونَ رِزۡقَكُمۡ أَنَّكُمۡ تُكَذِّبُونَ ﴾
[الوَاقِعة: 82]
﴿وتجعلون رزقكم أنكم تكذبون﴾ [الوَاقِعة: 82]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ẹ sì ń sọ ìdúpẹ́ arísìkí yín di pé dájúdájú ẹ̀ ń pe òdodo nírọ́ |