×

Oun ni Eni t’O n so awon ayah t’o yanju kale fun 57:9 Yoruba translation

Quran infoYorubaSurah Al-hadid ⮕ (57:9) ayat 9 in Yoruba

57:9 Surah Al-hadid ayat 9 in Yoruba (اليوربا)

Quran with Yoruba translation - Surah Al-hadid ayat 9 - الحدِيد - Page - Juz 27

﴿هُوَ ٱلَّذِي يُنَزِّلُ عَلَىٰ عَبۡدِهِۦٓ ءَايَٰتِۭ بَيِّنَٰتٖ لِّيُخۡرِجَكُم مِّنَ ٱلظُّلُمَٰتِ إِلَى ٱلنُّورِۚ وَإِنَّ ٱللَّهَ بِكُمۡ لَرَءُوفٞ رَّحِيمٞ ﴾
[الحدِيد: 9]

Oun ni Eni t’O n so awon ayah t’o yanju kale fun erusin Re nitori ki o le mu yin kuro ninu awon okunkun wa sinu imole. Dajudaju Allahu ni Alaaanu, Asake-orun fun yin

❮ Previous Next ❯

ترجمة: هو الذي ينـزل على عبده آيات بينات ليخرجكم من الظلمات إلى النور, باللغة اليوربا

﴿هو الذي ينـزل على عبده آيات بينات ليخرجكم من الظلمات إلى النور﴾ [الحدِيد: 9]

Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Òun ni Ẹni t’Ó ń sọ àwọn āyah t’ó yanjú kalẹ̀ fún ẹrúsìn Rẹ̀ nítorí kí ó lè mu yín kúrò nínú àwọn òkùnkùn wá sínú ìmọ́lẹ̀. Dájúdájú Allāhu ni Aláàánú, Àṣàkẹ́-ọ̀run fun yín
❮ Previous Next ❯

Verse in more languages

Transliteration Bangla Bosnian German English Persian French Hindi Indonesian Kazakh Dutch Russian Spanish Turkish Urdu Uzbek