×

Ki ni o mu yin ti eyin ko fi nii gba Allahu 57:8 Yoruba translation

Quran infoYorubaSurah Al-hadid ⮕ (57:8) ayat 8 in Yoruba

57:8 Surah Al-hadid ayat 8 in Yoruba (اليوربا)

Quran with Yoruba translation - Surah Al-hadid ayat 8 - الحدِيد - Page - Juz 27

﴿وَمَا لَكُمۡ لَا تُؤۡمِنُونَ بِٱللَّهِ وَٱلرَّسُولُ يَدۡعُوكُمۡ لِتُؤۡمِنُواْ بِرَبِّكُمۡ وَقَدۡ أَخَذَ مِيثَٰقَكُمۡ إِن كُنتُم مُّؤۡمِنِينَ ﴾
[الحدِيد: 8]

Ki ni o mu yin ti eyin ko fi nii gba Allahu gbo ni ododo? Ojise si n pe yin nitori ki e le gba Oluwa yin gbo. Allahu si ti gba adehun lowo yin, ti eyin ba je onigbagbo ododo

❮ Previous Next ❯

ترجمة: وما لكم لا تؤمنون بالله والرسول يدعوكم لتؤمنوا بربكم وقد أخذ ميثاقكم, باللغة اليوربا

﴿وما لكم لا تؤمنون بالله والرسول يدعوكم لتؤمنوا بربكم وقد أخذ ميثاقكم﴾ [الحدِيد: 8]

Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Kí ni ó mu yín tí ẹ̀yin kò fi níí gba Allāhu gbọ́ ní òdodo? Òjíṣẹ́ sì ń pè yín nítorí kí ẹ lè gba Olúwa yín gbọ́. Allāhu sì ti gba àdéhùn lọ́wọ́ yín, tí ẹ̀yin bá jẹ́ onígbàgbọ́ òdodo
❮ Previous Next ❯

Verse in more languages

Transliteration Bangla Bosnian German English Persian French Hindi Indonesian Kazakh Dutch Russian Spanish Turkish Urdu Uzbek