×

Dajudaju eyin ni erujeje t’o lagbara ju Allahu lo ninu igba-aya won. 59:13 Yoruba translation

Quran infoYorubaSurah Al-hashr ⮕ (59:13) ayat 13 in Yoruba

59:13 Surah Al-hashr ayat 13 in Yoruba (اليوربا)

Quran with Yoruba translation - Surah Al-hashr ayat 13 - الحَشر - Page - Juz 28

﴿لَأَنتُمۡ أَشَدُّ رَهۡبَةٗ فِي صُدُورِهِم مِّنَ ٱللَّهِۚ ذَٰلِكَ بِأَنَّهُمۡ قَوۡمٞ لَّا يَفۡقَهُونَ ﴾
[الحَشر: 13]

Dajudaju eyin ni erujeje t’o lagbara ju Allahu lo ninu igba-aya won. Iyen nitori pe dajudaju awon ni ijo ti ko gbo agboye

❮ Previous Next ❯

ترجمة: لأنتم أشد رهبة في صدورهم من الله ذلك بأنهم قوم لا يفقهون, باللغة اليوربا

﴿لأنتم أشد رهبة في صدورهم من الله ذلك بأنهم قوم لا يفقهون﴾ [الحَشر: 13]

Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Dájúdájú ẹ̀yin ni ẹ̀rùjẹ̀jẹ̀ t’ó lágbára ju Allāhu lọ nínú igbá-àyà wọn. Ìyẹn nítorí pé dájúdájú àwọn ni ìjọ tí kò gbọ́ àgbọ́yé
❮ Previous Next ❯

Verse in more languages

Transliteration Bangla Bosnian German English Persian French Hindi Indonesian Kazakh Dutch Russian Spanish Turkish Urdu Uzbek