×

E fi eyi t’o han ninu ese ati eyi t’o pamo ninu 6:120 Yoruba translation

Quran infoYorubaSurah Al-An‘am ⮕ (6:120) ayat 120 in Yoruba

6:120 Surah Al-An‘am ayat 120 in Yoruba (اليوربا)

Quran with Yoruba translation - Surah Al-An‘am ayat 120 - الأنعَام - Page - Juz 8

﴿وَذَرُواْ ظَٰهِرَ ٱلۡإِثۡمِ وَبَاطِنَهُۥٓۚ إِنَّ ٱلَّذِينَ يَكۡسِبُونَ ٱلۡإِثۡمَ سَيُجۡزَوۡنَ بِمَا كَانُواْ يَقۡتَرِفُونَ ﴾
[الأنعَام: 120]

E fi eyi t’o han ninu ese ati eyi t’o pamo ninu re sile. Dajudaju awon t’o n se ise ese, A oo san won ni esan ohun ti won n da lese

❮ Previous Next ❯

ترجمة: وذروا ظاهر الإثم وباطنه إن الذين يكسبون الإثم سيجزون بما كانوا يقترفون, باللغة اليوربا

﴿وذروا ظاهر الإثم وباطنه إن الذين يكسبون الإثم سيجزون بما كانوا يقترفون﴾ [الأنعَام: 120]

Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Ẹ fi èyí t’ó hàn nínú ẹ̀ṣẹ̀ àti èyí t’ó pamọ́ nínú rẹ̀ sílẹ̀. Dájúdájú àwọn t’ó ń ṣe iṣẹ́ ẹ̀ṣẹ̀, A óò san wọ́n ní ẹ̀san ohun tí wọ́n ń dá lẹ́ṣẹ̀
❮ Previous Next ❯

Verse in more languages

Transliteration Bangla Bosnian German English Persian French Hindi Indonesian Kazakh Dutch Russian Spanish Turkish Urdu Uzbek