Quran with Yoruba translation - Surah Al-An‘am ayat 162 - الأنعَام - Page - Juz 8
﴿قُلۡ إِنَّ صَلَاتِي وَنُسُكِي وَمَحۡيَايَ وَمَمَاتِي لِلَّهِ رَبِّ ٱلۡعَٰلَمِينَ ﴾
[الأنعَام: 162]
﴿قل إن صلاتي ونسكي ومحياي ومماتي لله رب العالمين﴾ [الأنعَام: 162]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Sọ pé: "Dájúdájú ìrun mi, ẹran (pípa) mi, ìṣẹ̀mí ayé mi àti ikú mi ń jẹ́ ti Allāhu, Olúwa gbogbo ẹ̀dá |