Quran with Yoruba translation - Surah Al-An‘am ayat 163 - الأنعَام - Page - Juz 8
﴿لَا شَرِيكَ لَهُۥۖ وَبِذَٰلِكَ أُمِرۡتُ وَأَنَا۠ أَوَّلُ ٱلۡمُسۡلِمِينَ ﴾
[الأنعَام: 163]
﴿لا شريك له وبذلك أمرت وأنا أول المسلمين﴾ [الأنعَام: 163]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Kò sí akẹgbẹ́ fún Un. Ìyẹn ni Wọ́n pa láṣẹ fún mi. Èmi sì ni ẹni-àkọ́kọ́ àwọn mùsùlùmí (ní àsìkò tèmi) |