Quran with Yoruba translation - Surah Al-An‘am ayat 18 - الأنعَام - Page - Juz 7
﴿وَهُوَ ٱلۡقَاهِرُ فَوۡقَ عِبَادِهِۦۚ وَهُوَ ٱلۡحَكِيمُ ٱلۡخَبِيرُ ﴾
[الأنعَام: 18]
﴿وهو القاهر فوق عباده وهو الحكيم الخبير﴾ [الأنعَام: 18]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Òun sì ni Olùborí t’Ó wà lókè àwọn ẹrú Rẹ̀. Òun ni Ọlọ́gbọ́n, Onímọ̀-ìkọ̀kọ̀ |