Quran with Yoruba translation - Surah Al-An‘am ayat 62 - الأنعَام - Page - Juz 7
﴿ثُمَّ رُدُّوٓاْ إِلَى ٱللَّهِ مَوۡلَىٰهُمُ ٱلۡحَقِّۚ أَلَا لَهُ ٱلۡحُكۡمُ وَهُوَ أَسۡرَعُ ٱلۡحَٰسِبِينَ ﴾
[الأنعَام: 62]
﴿ثم ردوا إلى الله مولاهم الحق ألا له الحكم وهو أسرع الحاسبين﴾ [الأنعَام: 62]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Lẹ́yìn náà, wọ́n yóò dá wọn padà sí ọ̀dọ̀ Allāhu, Olúwa wọn, Òdodo. Kíyè sí i, tiRẹ̀ ni ìdájọ́. Òun sì yára jùlọ nínú àwọn olùṣírò |