Quran with Yoruba translation - Surah Al-An‘am ayat 69 - الأنعَام - Page - Juz 7
﴿وَمَا عَلَى ٱلَّذِينَ يَتَّقُونَ مِنۡ حِسَابِهِم مِّن شَيۡءٖ وَلَٰكِن ذِكۡرَىٰ لَعَلَّهُمۡ يَتَّقُونَ ﴾
[الأنعَام: 69]
﴿وما على الذين يتقون من حسابهم من شيء ولكن ذكرى لعلهم يتقون﴾ [الأنعَام: 69]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Kiní kan nínú ìṣírò-iṣẹ́ wọn kò sí lọ́rùn àwọn t’ó ń bẹ̀rù (Allāhu), ṣùgbọ́n ìṣítí ni nítorí kí wọ́n lè ṣọ́ra (fún Iná) |