×

Oun si ni Eni ti O seda awon sanmo ati ile pelu 6:73 Yoruba translation

Quran infoYorubaSurah Al-An‘am ⮕ (6:73) ayat 73 in Yoruba

6:73 Surah Al-An‘am ayat 73 in Yoruba (اليوربا)

Quran with Yoruba translation - Surah Al-An‘am ayat 73 - الأنعَام - Page - Juz 7

﴿وَهُوَ ٱلَّذِي خَلَقَ ٱلسَّمَٰوَٰتِ وَٱلۡأَرۡضَ بِٱلۡحَقِّۖ وَيَوۡمَ يَقُولُ كُن فَيَكُونُۚ قَوۡلُهُ ٱلۡحَقُّۚ وَلَهُ ٱلۡمُلۡكُ يَوۡمَ يُنفَخُ فِي ٱلصُّورِۚ عَٰلِمُ ٱلۡغَيۡبِ وَٱلشَّهَٰدَةِۚ وَهُوَ ٱلۡحَكِيمُ ٱلۡخَبِيرُ ﴾
[الأنعَام: 73]

Oun si ni Eni ti O seda awon sanmo ati ile pelu ododo. Ati pe (ranti) ojo ti (Allahu maa yi ile ati sanmo pada si nnkan miiran), O si maa so pe: "Je bee." O si maa je bee. Ododo ni oro Re. TiRe si ni ijoba ni ojo ti won a fon fere oniwo fun ajinde. Onimo-ikoko ati gbangba ni. Oun si ni Ologbon, Alamotan

❮ Previous Next ❯

ترجمة: وهو الذي خلق السموات والأرض بالحق ويوم يقول كن فيكون قوله الحق, باللغة اليوربا

﴿وهو الذي خلق السموات والأرض بالحق ويوم يقول كن فيكون قوله الحق﴾ [الأنعَام: 73]

Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Òun sì ni Ẹni tí Ó ṣẹ̀dá àwọn sánmọ̀ àti ilẹ̀ pẹ̀lú òdodo. Àti pé (rántí) ọjọ́ tí (Allāhu máa yí ilẹ̀ àti sánmọ̀ padà sí n̄ǹkan mìíràn), Ó sì máa sọ pé: "Jẹ́ bẹ́ẹ̀." Ó sì máa jẹ́ bẹ́ẹ̀. Òdodo ni ọ̀rọ̀ Rẹ̀. TiRẹ̀ sì ni ìjọba ní ọjọ́ tí wọ́n á fọn fèrè oníwo fún àjíǹde. Onímọ̀-ìkọ̀kọ̀ àti gban̄gba ni. Òun sì ni Ọlọ́gbọ́n, Alámọ̀tán
❮ Previous Next ❯

Verse in more languages

Transliteration Bangla Bosnian German English Persian French Hindi Indonesian Kazakh Dutch Russian Spanish Turkish Urdu Uzbek