Quran with Yoruba translation - Surah Al-An‘am ayat 72 - الأنعَام - Page - Juz 7
﴿وَأَنۡ أَقِيمُواْ ٱلصَّلَوٰةَ وَٱتَّقُوهُۚ وَهُوَ ٱلَّذِيٓ إِلَيۡهِ تُحۡشَرُونَ ﴾
[الأنعَام: 72]
﴿وأن أقيموا الصلاة واتقوه وهو الذي إليه تحشرون﴾ [الأنعَام: 72]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Àti pé kí ẹ kírun, kí ẹ sì bẹ̀rù Allāhu. Òun ni Ẹni tí wọ́n yóò ko yín jọ sí ọ̀dọ̀ Rẹ̀ |