×

Awon eniyan re si ja a niyan. O so pe: "Se eyin 6:80 Yoruba translation

Quran infoYorubaSurah Al-An‘am ⮕ (6:80) ayat 80 in Yoruba

6:80 Surah Al-An‘am ayat 80 in Yoruba (اليوربا)

Quran with Yoruba translation - Surah Al-An‘am ayat 80 - الأنعَام - Page - Juz 7

﴿وَحَآجَّهُۥ قَوۡمُهُۥۚ قَالَ أَتُحَٰٓجُّوٓنِّي فِي ٱللَّهِ وَقَدۡ هَدَىٰنِۚ وَلَآ أَخَافُ مَا تُشۡرِكُونَ بِهِۦٓ إِلَّآ أَن يَشَآءَ رَبِّي شَيۡـٔٗاۚ وَسِعَ رَبِّي كُلَّ شَيۡءٍ عِلۡمًاۚ أَفَلَا تَتَذَكَّرُونَ ﴾
[الأنعَام: 80]

Awon eniyan re si ja a niyan. O so pe: "Se eyin yoo ja mi niyan nipa Allahu, O si ti fi ona mo mi? Emi ko si paya (awon orisa) ti e so di akegbe fun Un, afi bi Allahu ba fe kini kan (pe ko sele). Oluwa mi fi imo gbooro ju gbogbo nnkan. Nitori naa, se e o nii lo iranti ni

❮ Previous Next ❯

ترجمة: وحاجه قومه قال أتحاجوني في الله وقد هدان ولا أخاف ما تشركون, باللغة اليوربا

﴿وحاجه قومه قال أتحاجوني في الله وقد هدان ولا أخاف ما تشركون﴾ [الأنعَام: 80]

Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Àwọn ènìyàn rẹ̀ sì jà á níyàn. Ó sọ pé: "Ṣé ẹ̀yin yóò jà mí níyàn nípa Allāhu, Ó sì ti fi ọ̀nà mọ̀ mí? Èmi kò sì páyà (àwọn òrìṣà) tí ẹ sọ di akẹgbẹ́ fún Un, àfi bí Allāhu bá fẹ́ kiní kan (pé kó ṣẹlẹ̀). Olúwa mi fi ìmọ̀ gbòòrò ju gbogbo n̄ǹkan. Nítorí náà, ṣé ẹ ò níí lo ìrántí ni
❮ Previous Next ❯

Verse in more languages

Transliteration Bangla Bosnian German English Persian French Hindi Indonesian Kazakh Dutch Russian Spanish Turkish Urdu Uzbek