Quran with Yoruba translation - Surah Al-An‘am ayat 98 - الأنعَام - Page - Juz 7
﴿وَهُوَ ٱلَّذِيٓ أَنشَأَكُم مِّن نَّفۡسٖ وَٰحِدَةٖ فَمُسۡتَقَرّٞ وَمُسۡتَوۡدَعٞۗ قَدۡ فَصَّلۡنَا ٱلۡأٓيَٰتِ لِقَوۡمٖ يَفۡقَهُونَ ﴾
[الأنعَام: 98]
﴿وهو الذي أنشأكم من نفس واحدة فمستقر ومستودع قد فصلنا الآيات لقوم﴾ [الأنعَام: 98]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Òun ni Ẹni tí Ó ṣẹ̀dá yín láti ara ẹ̀mí ẹyọ kan. Nítorí náà, ibùgbé (nílé ayé) àti ibùpadàsí (ní ọ̀run wà fun yín). A kúkú ti ṣàlàyé àwọn āyah fún àwọn ènìyàn t’ó ní àgbọ́yé |