×

O le je pe Allahu yoo fi ife si aarin eyin ati 60:7 Yoruba translation

Quran infoYorubaSurah Al-Mumtahanah ⮕ (60:7) ayat 7 in Yoruba

60:7 Surah Al-Mumtahanah ayat 7 in Yoruba (اليوربا)

Quran with Yoruba translation - Surah Al-Mumtahanah ayat 7 - المُمتَحنَة - Page - Juz 28

﴿۞ عَسَى ٱللَّهُ أَن يَجۡعَلَ بَيۡنَكُمۡ وَبَيۡنَ ٱلَّذِينَ عَادَيۡتُم مِّنۡهُم مَّوَدَّةٗۚ وَٱللَّهُ قَدِيرٞۚ وَٱللَّهُ غَفُورٞ رَّحِيمٞ ﴾
[المُمتَحنَة: 7]

O le je pe Allahu yoo fi ife si aarin eyin ati awon ti e mu ni ota ninu won (iyen, nigba ti won ba di musulumi). Allahu ni Alagbara. Allahu si ni Alaforijin, Asake-orun

❮ Previous Next ❯

ترجمة: عسى الله أن يجعل بينكم وبين الذين عاديتم منهم مودة والله قدير, باللغة اليوربا

﴿عسى الله أن يجعل بينكم وبين الذين عاديتم منهم مودة والله قدير﴾ [المُمتَحنَة: 7]

Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Ó lè jẹ́ pé Allāhu yóò fi ìfẹ́ sí ààrin ẹ̀yin àti àwọn tí ẹ mú ní ọ̀tá nínú wọn (ìyẹn, nígbà tí wọ́n bá di mùsùlùmí). Allāhu ni Alágbára. Allāhu sì ni Aláforíjìn, Àṣàkẹ́-ọ̀run
❮ Previous Next ❯

Verse in more languages

Transliteration Bangla Bosnian German English Persian French Hindi Indonesian Kazakh Dutch Russian Spanish Turkish Urdu Uzbek