Quran with Yoruba translation - Surah Al-Mumtahanah ayat 6 - المُمتَحنَة - Page - Juz 28
﴿لَقَدۡ كَانَ لَكُمۡ فِيهِمۡ أُسۡوَةٌ حَسَنَةٞ لِّمَن كَانَ يَرۡجُواْ ٱللَّهَ وَٱلۡيَوۡمَ ٱلۡأٓخِرَۚ وَمَن يَتَوَلَّ فَإِنَّ ٱللَّهَ هُوَ ٱلۡغَنِيُّ ٱلۡحَمِيدُ ﴾
[المُمتَحنَة: 6]
﴿لقد كان لكم فيهم أسوة حسنة لمن كان يرجو الله واليوم الآخر﴾ [المُمتَحنَة: 6]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Dájúdájú àwòkọ́ṣe rere ti wà fun yín ní ara wọn fún ẹni t’ó ń retí (ẹ̀sán) Allāhu àti Ọjọ́ Ìkẹ́yìn. Ẹnikẹ́ni tí ó bá pẹ̀yìn dà, dájúdájú Allāhu, Òun ni Ọlọ́rọ̀, Ẹlẹ́yìn |