×

Bakan naa ni fun won; yala o ba won toro aforijin tabi 63:6 Yoruba translation

Quran infoYorubaSurah Al-Munafiqun ⮕ (63:6) ayat 6 in Yoruba

63:6 Surah Al-Munafiqun ayat 6 in Yoruba (اليوربا)

Quran with Yoruba translation - Surah Al-Munafiqun ayat 6 - المُنَافِقُونَ - Page - Juz 28

﴿سَوَآءٌ عَلَيۡهِمۡ أَسۡتَغۡفَرۡتَ لَهُمۡ أَمۡ لَمۡ تَسۡتَغۡفِرۡ لَهُمۡ لَن يَغۡفِرَ ٱللَّهُ لَهُمۡۚ إِنَّ ٱللَّهَ لَا يَهۡدِي ٱلۡقَوۡمَ ٱلۡفَٰسِقِينَ ﴾
[المُنَافِقُونَ: 6]

Bakan naa ni fun won; yala o ba won toro aforijin tabi o o ba won toro aforijin. Allahu ko nii forijin won. Dajudaju Allahu ko nii fi ona mo ijo obileje

❮ Previous Next ❯

ترجمة: سواء عليهم أستغفرت لهم أم لم تستغفر لهم لن يغفر الله لهم, باللغة اليوربا

﴿سواء عليهم أستغفرت لهم أم لم تستغفر لهم لن يغفر الله لهم﴾ [المُنَافِقُونَ: 6]

Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Bákan náà ni fún wọn; yálà o bá wọn tọrọ àforíjìn tàbí o ò bá wọn tọrọ àforíjìn. Allāhu kò níí foríjìn wọ́n. Dájúdájú Allāhu kò nií fi ọ̀nà mọ ìjọ òbìlẹ̀jẹ́
❮ Previous Next ❯

Verse in more languages

Transliteration Bangla Bosnian German English Persian French Hindi Indonesian Kazakh Dutch Russian Spanish Turkish Urdu Uzbek