×

Ati Moryam omobinrin ‘Imron, eyi ti o so abe re. A si 66:12 Yoruba translation

Quran infoYorubaSurah At-Tahrim ⮕ (66:12) ayat 12 in Yoruba

66:12 Surah At-Tahrim ayat 12 in Yoruba (اليوربا)

Quran with Yoruba translation - Surah At-Tahrim ayat 12 - التَّحرِيم - Page - Juz 28

﴿وَمَرۡيَمَ ٱبۡنَتَ عِمۡرَٰنَ ٱلَّتِيٓ أَحۡصَنَتۡ فَرۡجَهَا فَنَفَخۡنَا فِيهِ مِن رُّوحِنَا وَصَدَّقَتۡ بِكَلِمَٰتِ رَبِّهَا وَكُتُبِهِۦ وَكَانَتۡ مِنَ ٱلۡقَٰنِتِينَ ﴾
[التَّحرِيم: 12]

Ati Moryam omobinrin ‘Imron, eyi ti o so abe re. A si fe ategun si i lara ninu ategun emi ti A da. O gbagbo lododo ninu awon oro Oluwa re ati awon Tira Re. O si wa ninu awon olutele-ase Allahu

❮ Previous Next ❯

ترجمة: ومريم ابنة عمران التي أحصنت فرجها فنفخنا فيه من روحنا وصدقت بكلمات, باللغة اليوربا

﴿ومريم ابنة عمران التي أحصنت فرجها فنفخنا فيه من روحنا وصدقت بكلمات﴾ [التَّحرِيم: 12]

Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Àti Mọryam ọmọbìnrin ‘Imrọ̄n, èyí tí ó ṣọ́ abẹ́ rẹ̀. A sì fẹ́ atẹ́gùn sí i lára nínú atẹ́gùn ẹ̀mí tí A dá. Ó gbàgbọ́ lódodo nínú àwọn ọ̀rọ̀ Olúwa rẹ̀ àti àwọn Tírà Rẹ̀. Ó sì wà nínú àwọn olùtẹ̀lé-àṣẹ Allāhu
❮ Previous Next ❯

Verse in more languages

Transliteration Bangla Bosnian German English Persian French Hindi Indonesian Kazakh Dutch Russian Spanish Turkish Urdu Uzbek