Quran with Yoruba translation - Surah Al-Mulk ayat 7 - المُلك - Page - Juz 29
﴿إِذَآ أُلۡقُواْ فِيهَا سَمِعُواْ لَهَا شَهِيقٗا وَهِيَ تَفُورُ ﴾
[المُلك: 7]
﴿إذا ألقوا فيها سمعوا لها شهيقا وهي تفور﴾ [المُلك: 7]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Nígbà tí wọ́n bá jù wọ́n sínú rẹ̀, wọn yóò máa gbọ́ kíkùn rẹ̀, tí ó sì máa ru sókè |