Quran with Yoruba translation - Surah Al-Mulk ayat 6 - المُلك - Page - Juz 29
﴿وَلِلَّذِينَ كَفَرُواْ بِرَبِّهِمۡ عَذَابُ جَهَنَّمَۖ وَبِئۡسَ ٱلۡمَصِيرُ ﴾
[المُلك: 6]
﴿وللذين كفروا بربهم عذاب جهنم وبئس المصير﴾ [المُلك: 6]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ìyà iná Jahanamọ sì wà fún àwọn t’ó ṣàì gbàgbọ́. Ìkángun náà sì burú |