Quran with Yoruba translation - Surah Al-Qalam ayat 26 - القَلَم - Page - Juz 29
﴿فَلَمَّا رَأَوۡهَا قَالُوٓاْ إِنَّا لَضَآلُّونَ ﴾
[القَلَم: 26]
﴿فلما رأوها قالوا إنا لضالون﴾ [القَلَم: 26]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Nígbà tí wọ́n rí i, wọ́n wí pé: "Dájúdájú àwa ti ṣìnà |