Quran with Yoruba translation - Surah Al-Qalam ayat 50 - القَلَم - Page - Juz 29
﴿فَٱجۡتَبَٰهُ رَبُّهُۥ فَجَعَلَهُۥ مِنَ ٱلصَّٰلِحِينَ ﴾
[القَلَم: 50]
﴿فاجتباه ربه فجعله من الصالحين﴾ [القَلَم: 50]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Nítorí náà, Olúwa rẹ̀ ṣà á lẹ́ṣà. Ó sì ṣe é ní ara àwọn ẹni rere |