Quran with Yoruba translation - Surah Al-Qalam ayat 49 - القَلَم - Page - Juz 29
﴿لَّوۡلَآ أَن تَدَٰرَكَهُۥ نِعۡمَةٞ مِّن رَّبِّهِۦ لَنُبِذَ بِٱلۡعَرَآءِ وَهُوَ مَذۡمُومٞ ﴾
[القَلَم: 49]
﴿لولا أن تداركه نعمة من ربه لنبذ بالعراء وهو مذموم﴾ [القَلَم: 49]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Tí kò bá jẹ́ pé ìkẹ́ kan láti ọ̀dọ̀ Olúwa rẹ̀ lé e bá, wọn ìbá jù ú sórí ilẹ̀ gban̄sasa (láti inú ẹja) ní ẹni-èébú |