Quran with Yoruba translation - Surah Al-haqqah ayat 6 - الحَاقة - Page - Juz 29
﴿وَأَمَّا عَادٞ فَأُهۡلِكُواْ بِرِيحٖ صَرۡصَرٍ عَاتِيَةٖ ﴾
[الحَاقة: 6]
﴿وأما عاد فأهلكوا بريح صرصر عاتية﴾ [الحَاقة: 6]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ní ti ìjọ ‘Ād, wọ́n fi atẹ́gùn líle t’ó tayọ ẹnu-àlà pa wọ́n rẹ́ |