Quran with Yoruba translation - Surah Al-A‘raf ayat 108 - الأعرَاف - Page - Juz 9
﴿وَنَزَعَ يَدَهُۥ فَإِذَا هِيَ بَيۡضَآءُ لِلنَّٰظِرِينَ ﴾
[الأعرَاف: 108]
﴿ونـزع يده فإذا هي بيضاء للناظرين﴾ [الأعرَاف: 108]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ó tún fa ọwọ́ rẹ̀ yọ, ó sì di funfun (gbòlà) fún àwọn olùwòran |