Quran with Yoruba translation - Surah Al-A‘raf ayat 174 - الأعرَاف - Page - Juz 9
﴿وَكَذَٰلِكَ نُفَصِّلُ ٱلۡأٓيَٰتِ وَلَعَلَّهُمۡ يَرۡجِعُونَ ﴾
[الأعرَاف: 174]
﴿وكذلك نفصل الآيات ولعلهم يرجعون﴾ [الأعرَاف: 174]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Báyẹn ni A ṣe ń ṣàlàyé àwọn āyah Wa, nítorí kí wọ́n lè ṣẹ́rí padà (síbi òdodo) |