Quran with Yoruba translation - Surah Al-A‘raf ayat 192 - الأعرَاف - Page - Juz 9
﴿وَلَا يَسۡتَطِيعُونَ لَهُمۡ نَصۡرٗا وَلَآ أَنفُسَهُمۡ يَنصُرُونَ ﴾
[الأعرَاف: 192]
﴿ولا يستطيعون لهم نصرا ولا أنفسهم ينصرون﴾ [الأعرَاف: 192]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Àwọn òrìṣà kò lè ṣe àrànṣe kan fún àwọn abọ̀rìṣà. Àti pé àwọn òrìṣà gan-an kò lè ṣe àrànṣe fún ẹ̀mí ara wọ́n |