Quran with Yoruba translation - Surah Al-A‘raf ayat 200 - الأعرَاف - Page - Juz 9
﴿وَإِمَّا يَنزَغَنَّكَ مِنَ ٱلشَّيۡطَٰنِ نَزۡغٞ فَٱسۡتَعِذۡ بِٱللَّهِۚ إِنَّهُۥ سَمِيعٌ عَلِيمٌ ﴾
[الأعرَاف: 200]
﴿وإما ينـزغنك من الشيطان نـزغ فاستعذ بالله إنه سميع عليم﴾ [الأعرَاف: 200]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Tí ìbínú òdì kan bá sì ṣẹ́rí sínú ọkàn rẹ̀ láti ọ̀dọ̀ Èṣù, sá di Allāhu. Dájúdájú Òun ní Olùgbọ́, Onímọ̀ |