Quran with Yoruba translation - Surah Al-A‘raf ayat 199 - الأعرَاف - Page - Juz 9
﴿خُذِ ٱلۡعَفۡوَ وَأۡمُرۡ بِٱلۡعُرۡفِ وَأَعۡرِضۡ عَنِ ٱلۡجَٰهِلِينَ ﴾
[الأعرَاف: 199]
﴿خذ العفو وأمر بالعرف وأعرض عن الجاهلين﴾ [الأعرَاف: 199]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ṣàmójúkúrò, pàṣẹ ohun rere, kí o sì ṣẹ́rí kúrò lọ́dọ̀ àwọn aláìmọ̀kan |