Quran with Yoruba translation - Surah Al-A‘raf ayat 76 - الأعرَاف - Page - Juz 8
﴿قَالَ ٱلَّذِينَ ٱسۡتَكۡبَرُوٓاْ إِنَّا بِٱلَّذِيٓ ءَامَنتُم بِهِۦ كَٰفِرُونَ ﴾
[الأعرَاف: 76]
﴿قال الذين استكبروا إنا بالذي آمنتم به كافرون﴾ [الأعرَاف: 76]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Àwọn t’ó ṣègbéraga wí pé: “Dájúdájú àwa ṣàì gbàgbọ́ nínú ohun tí ẹ̀yin gbàgbọ́.” |