Quran with Yoruba translation - Surah Nuh ayat 10 - نُوح - Page - Juz 29
﴿فَقُلۡتُ ٱسۡتَغۡفِرُواْ رَبَّكُمۡ إِنَّهُۥ كَانَ غَفَّارٗا ﴾
[نُوح: 10]
﴿فقلت استغفروا ربكم إنه كان غفارا﴾ [نُوح: 10]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Mo sì sọ pé, ẹ tọrọ àforíjìn ní ọ̀dọ̀ Olúwa yín, dájúdájú Ó ń jẹ́ Aláforíjìn |