Quran with Yoruba translation - Surah Nuh ayat 9 - نُوح - Page - Juz 29
﴿ثُمَّ إِنِّيٓ أَعۡلَنتُ لَهُمۡ وَأَسۡرَرۡتُ لَهُمۡ إِسۡرَارٗا ﴾
[نُوح: 9]
﴿ثم إني أعلنت لهم وأسررت لهم إسرارا﴾ [نُوح: 9]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Lẹ́yìn náà, dájúdájú èmi kéde fún wọn, mo sì tún pè wọ́n ní ìdá kọ́ńkọ́ |