Quran with Yoruba translation - Surah Al-Jinn ayat 16 - الجِن - Page - Juz 29
﴿وَأَلَّوِ ٱسۡتَقَٰمُواْ عَلَى ٱلطَّرِيقَةِ لَأَسۡقَيۡنَٰهُم مَّآءً غَدَقٗا ﴾
[الجِن: 16]
﴿وألو استقاموا على الطريقة لأسقيناهم ماء غدقا﴾ [الجِن: 16]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Àti pé tí ó bá jẹ́ pé wọ́n dúró ṣinṣin lójú ọ̀nà (’Islām) ni, dájúdájú Àwa ìbá fún wọn ní omi púpọ̀ mu |