Quran with Yoruba translation - Surah Al-Muzzammil ayat 14 - المُزمل - Page - Juz 29
﴿يَوۡمَ تَرۡجُفُ ٱلۡأَرۡضُ وَٱلۡجِبَالُ وَكَانَتِ ٱلۡجِبَالُ كَثِيبٗا مَّهِيلًا ﴾
[المُزمل: 14]
﴿يوم ترجف الأرض والجبال وكانت الجبال كثيبا مهيلا﴾ [المُزمل: 14]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ní ọjọ́ tí ilẹ̀ àti àwọn àpáta yóò máa mì tìtì pẹ̀lú ohùn igbe líle. Àwọn àpáta sì máa di yanrìn tí wọ́n kójọ tí wọ́n túká |