Quran with Yoruba translation - Surah Al-Insan ayat 26 - الإنسَان - Page - Juz 29
﴿وَمِنَ ٱلَّيۡلِ فَٱسۡجُدۡ لَهُۥ وَسَبِّحۡهُ لَيۡلٗا طَوِيلًا ﴾
[الإنسَان: 26]
﴿ومن الليل فاسجد له وسبحه ليلا طويلا﴾ [الإنسَان: 26]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Àti ní òru, forí kanlẹ̀ fún Un. Kí o sì ṣàfọ̀mọ́ fún Un ní òru fún ìgbà pípẹ́ |