Quran with Yoruba translation - Surah An-Nazi‘at ayat 40 - النَّازعَات - Page - Juz 30
﴿وَأَمَّا مَنۡ خَافَ مَقَامَ رَبِّهِۦ وَنَهَى ٱلنَّفۡسَ عَنِ ٱلۡهَوَىٰ ﴾
[النَّازعَات: 40]
﴿وأما من خاف مقام ربه ونهى النفس عن الهوى﴾ [النَّازعَات: 40]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ní ti ẹni tí ó bá páyà ìdúró níwájú Olúwa rẹ̀, tí ó tún kọ ìfẹ́-inú fún ẹ̀mí (ara rẹ̀) |