×

Won n bi o leere nipa oro ogun. So pe: “Oro ogun 8:1 Yoruba translation

Quran infoYorubaSurah Al-Anfal ⮕ (8:1) ayat 1 in Yoruba

8:1 Surah Al-Anfal ayat 1 in Yoruba (اليوربا)

Quran with Yoruba translation - Surah Al-Anfal ayat 1 - الأنفَال - Page - Juz 9

﴿يَسۡـَٔلُونَكَ عَنِ ٱلۡأَنفَالِۖ قُلِ ٱلۡأَنفَالُ لِلَّهِ وَٱلرَّسُولِۖ فَٱتَّقُواْ ٱللَّهَ وَأَصۡلِحُواْ ذَاتَ بَيۡنِكُمۡۖ وَأَطِيعُواْ ٱللَّهَ وَرَسُولَهُۥٓ إِن كُنتُم مُّؤۡمِنِينَ ﴾
[الأنفَال: 1]

Won n bi o leere nipa oro ogun. So pe: “Oro ogun je ti Allahu ati ti Ojise. Nitori naa, e beru Allahu. Ki e si se atunse nnkan ti n be laaarin yin. E tele ti Allahu ati Ojise Re ti e ba je onigbagbo ododo

❮ Previous Next ❯

ترجمة: يسألونك عن الأنفال قل الأنفال لله والرسول فاتقوا الله وأصلحوا ذات بينكم, باللغة اليوربا

﴿يسألونك عن الأنفال قل الأنفال لله والرسول فاتقوا الله وأصلحوا ذات بينكم﴾ [الأنفَال: 1]

Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Wọ́n ń bi ọ́ léèrè nípa ọrọ̀ ogun. Sọ pé: “Ọrọ̀ ogun jẹ́ ti Allāhu àti ti Òjíṣẹ́. Nítorí náà, ẹ bẹ̀rù Allāhu. Kí ẹ sì ṣe àtúnṣe n̄ǹkan tí ń bẹ láààrin yín. Ẹ tẹ̀lé ti Allāhu àti Òjíṣẹ́ Rẹ̀ tí ẹ bá jẹ́ onígbàgbọ́ òdodo
❮ Previous Next ❯

Verse in more languages

Transliteration Bangla Bosnian German English Persian French Hindi Indonesian Kazakh Dutch Russian Spanish Turkish Urdu Uzbek