Quran with Yoruba translation - Surah Al-Anfal ayat 67 - الأنفَال - Page - Juz 10
﴿مَا كَانَ لِنَبِيٍّ أَن يَكُونَ لَهُۥٓ أَسۡرَىٰ حَتَّىٰ يُثۡخِنَ فِي ٱلۡأَرۡضِۚ تُرِيدُونَ عَرَضَ ٱلدُّنۡيَا وَٱللَّهُ يُرِيدُ ٱلۡأٓخِرَةَۗ وَٱللَّهُ عَزِيزٌ حَكِيمٞ ﴾
[الأنفَال: 67]
﴿ما كان لنبي أن يكون له أسرى حتى يثخن في الأرض تريدون﴾ [الأنفَال: 67]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Kò lẹ́tọ̀ọ́ fún Ànábì kan láti ní ẹrú ogun (kí ó sì tú wọn sílẹ̀ pẹ̀lú owó ìtúsílẹ̀) títí ó fi máa ṣẹ́gun (wọn) tán pátápátá lórí ilẹ̀. Ẹ̀yin ń fẹ́ ìgbádùn ayé, Allāhu sì ń fẹ́ ọ̀run. Allāhu sì ni Alágbára, Ọlọ́gbọ́n |