Quran with Yoruba translation - Surah ‘Abasa ayat 8 - عَبَسَ - Page - Juz 30
﴿وَأَمَّا مَن جَآءَكَ يَسۡعَىٰ ﴾
[عَبَسَ: 8]
﴿وأما من جاءك يسعى﴾ [عَبَسَ: 8]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ní ti ẹni tí ó sì wá bá ọ, t’ó ń yára gágá (sí ìrántí, ìyẹn afọ́jú) |