×

Gbogbo awon musulumi ko si gbodo da lo si oju ogun esin. 9:122 Yoruba translation

Quran infoYorubaSurah At-Taubah ⮕ (9:122) ayat 122 in Yoruba

9:122 Surah At-Taubah ayat 122 in Yoruba (اليوربا)

Quran with Yoruba translation - Surah At-Taubah ayat 122 - التوبَة - Page - Juz 11

﴿۞ وَمَا كَانَ ٱلۡمُؤۡمِنُونَ لِيَنفِرُواْ كَآفَّةٗۚ فَلَوۡلَا نَفَرَ مِن كُلِّ فِرۡقَةٖ مِّنۡهُمۡ طَآئِفَةٞ لِّيَتَفَقَّهُواْ فِي ٱلدِّينِ وَلِيُنذِرُواْ قَوۡمَهُمۡ إِذَا رَجَعُوٓاْ إِلَيۡهِمۡ لَعَلَّهُمۡ يَحۡذَرُونَ ﴾
[التوبَة: 122]

Gbogbo awon musulumi ko si gbodo da lo si oju ogun esin. Iba suwon ki igun kan ninu won ninu iko kookan jade lati wa agboye nipa esin, ki won si maa se ikilo fun awon eniyan won nigba ti won ba pada sodo won boya won yo le sora se

❮ Previous Next ❯

ترجمة: وما كان المؤمنون لينفروا كافة فلولا نفر من كل فرقة منهم طائفة, باللغة اليوربا

﴿وما كان المؤمنون لينفروا كافة فلولا نفر من كل فرقة منهم طائفة﴾ [التوبَة: 122]

Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Gbogbo àwọn mùsùlùmí kò sì gbọdọ̀ dà lọ sí ojú ogun ẹ̀sìn. Ìbá ṣuwọ̀n kí igun kan nínú wọn nínú ikọ̀ kọ̀ọ̀kan jáde láti wá àgbọ́yé nípa ẹ̀sìn, kí wọ́n sì máa ṣe ìkìlọ̀ fún àwọn ènìyàn wọn nígbà tí wọ́n bá padà sọ́dọ̀ wọn bóyá wọn yó lè ṣọ́ra ṣe
❮ Previous Next ❯

Verse in more languages

Transliteration Bangla Bosnian German English Persian French Hindi Indonesian Kazakh Dutch Russian Spanish Turkish Urdu Uzbek