×

Awon yehudi wi pe: "‘Uzaer ni omo Allahu." Awon nasara si wi 9:30 Yoruba translation

Quran infoYorubaSurah At-Taubah ⮕ (9:30) ayat 30 in Yoruba

9:30 Surah At-Taubah ayat 30 in Yoruba (اليوربا)

Quran with Yoruba translation - Surah At-Taubah ayat 30 - التوبَة - Page - Juz 10

﴿وَقَالَتِ ٱلۡيَهُودُ عُزَيۡرٌ ٱبۡنُ ٱللَّهِ وَقَالَتِ ٱلنَّصَٰرَى ٱلۡمَسِيحُ ٱبۡنُ ٱللَّهِۖ ذَٰلِكَ قَوۡلُهُم بِأَفۡوَٰهِهِمۡۖ يُضَٰهِـُٔونَ قَوۡلَ ٱلَّذِينَ كَفَرُواْ مِن قَبۡلُۚ قَٰتَلَهُمُ ٱللَّهُۖ أَنَّىٰ يُؤۡفَكُونَ ﴾
[التوبَة: 30]

Awon yehudi wi pe: "‘Uzaer ni omo Allahu." Awon nasara si wi pe: "Mosih ni omo Allahu." Iyen ni oro won ni enu won. Won n fi jo oro awon t’o sai gbagbo siwaju (won). Allahu fi won gegun-un. Bawo ni won se n seri won kuro nibi ododo

❮ Previous Next ❯

ترجمة: وقالت اليهود عزير ابن الله وقالت النصارى المسيح ابن الله ذلك قولهم, باللغة اليوربا

﴿وقالت اليهود عزير ابن الله وقالت النصارى المسيح ابن الله ذلك قولهم﴾ [التوبَة: 30]

Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Àwọn yẹhudi wí pé: "‘Uzaer ni ọmọ Allāhu." Àwọn nasara sì wí pé: "Mọsīh ni ọmọ Allāhu." Ìyẹn ni ọ̀rọ̀ wọn ní ẹnu wọn. Wọ́n ń fi jọ ọ̀rọ̀ àwọn t’ó ṣàì gbàgbọ́ ṣíwájú (wọn). Allāhu fi wọ́n gégùn-ún. Báwo ni wọ́n ṣe ń ṣẹ́rí wọn kúrò níbi òdodo
❮ Previous Next ❯

Verse in more languages

Transliteration Bangla Bosnian German English Persian French Hindi Indonesian Kazakh Dutch Russian Spanish Turkish Urdu Uzbek