×

Se won ko mo pe Allahu mo asiri won ati oro ateso 9:78 Yoruba translation

Quran infoYorubaSurah At-Taubah ⮕ (9:78) ayat 78 in Yoruba

9:78 Surah At-Taubah ayat 78 in Yoruba (اليوربا)

Quran with Yoruba translation - Surah At-Taubah ayat 78 - التوبَة - Page - Juz 10

﴿أَلَمۡ يَعۡلَمُوٓاْ أَنَّ ٱللَّهَ يَعۡلَمُ سِرَّهُمۡ وَنَجۡوَىٰهُمۡ وَأَنَّ ٱللَّهَ عَلَّٰمُ ٱلۡغُيُوبِ ﴾
[التوبَة: 78]

Se won ko mo pe Allahu mo asiri won ati oro ateso won, ati pe dajudaju Allahu ni Onimo nipa awon ikoko

❮ Previous Next ❯

ترجمة: ألم يعلموا أن الله يعلم سرهم ونجواهم وأن الله علام الغيوب, باللغة اليوربا

﴿ألم يعلموا أن الله يعلم سرهم ونجواهم وأن الله علام الغيوب﴾ [التوبَة: 78]

Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Ṣé wọn kò mọ̀ pé Allāhu mọ àṣírí wọn àti ọ̀rọ̀ àtẹ̀sọ wọn, àti pé dájúdájú Allāhu ni Onímọ̀ nípa àwọn ìkọ̀kọ̀
❮ Previous Next ❯

Verse in more languages

Transliteration Bangla Bosnian German English Persian French Hindi Indonesian Kazakh Dutch Russian Spanish Turkish Urdu Uzbek