Quran with Yoruba translation - Surah Ash-Shams ayat 13 - الشَّمس - Page - Juz 30
﴿فَقَالَ لَهُمۡ رَسُولُ ٱللَّهِ نَاقَةَ ٱللَّهِ وَسُقۡيَٰهَا ﴾
[الشَّمس: 13]
﴿فقال لهم رسول الله ناقة الله وسقياها﴾ [الشَّمس: 13]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Nígbà náà, Òjíṣẹ́ Allāhu sọ fún wọn pé: "(Ẹ fi) abo ràkúnmí Allāhu àti omi rẹ̀ (sílẹ̀) |